ọrọ-iṣe
Yoruba
editAlternative forms
editEtymology
editFrom ọ̀rọ̀ (“word”) + ìṣe (“action”), literally “action word”.
Pronunciation
editNoun
editọ̀rọ̀-ìṣe
- verb
- Kí ni ìtumọ̀ ọ̀rọ̀-ìṣe èdè Gẹ̀ẹ́sí "to meet"?
- What is the meaning of the English verb, "to meet"?
- 2015 April 27, L.O. Adéwọlé, “Gírámà Gẹ̀ẹ́sì fún Àwọn Alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ (English Grammar for Beginners) - Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ Kejì (Second Lecture)”, in Yoruba for Academic Purpose[1]:
- Oriṣìí Ọ̀rọ̀-ìṣe (Verb Types)
Oríṣìí ọ̀rọ̀-ìṣe (verb) mẹ́ta ni ó wà. Àwọn náà ni aláìgbàbọ̀ (intransitive), asopọ̀ (linking) àti agbàbọ̀ (transitive).- Verb Types
There are three types of verbs. They are intransitive verbs, linking verbs, and transitive verbs.
- Verb Types
Hyponyms
edit- agbẹ̀yìn ọ̀rọ̀-ìṣe (“post verb”)
- aṣáájú ọ̀rọ̀-ìṣe (“preverb”)
- ọ̀rọ̀-ìṣe abọ́dé (“simple verb”)
- ọ̀rọ̀-ìṣe abáṣelọ (“action verb”)
- ọ̀rọ̀-ìṣe agbàbọ̀ (“symmetrical verb”)
- ọ̀rọ̀-ìṣe alápèpadà (“echoing verb”)
- ọ̀rọ̀-ìṣe aláìbáṣelọ (“stative verb”)
- ọ̀rọ̀-ìṣe aláìgbàbọ̀ (“intransitive verb”)
- ọ̀rọ̀-ìṣe asolùwàdàbọ̀ (“symmetrical verb”)
- ọ̀rọ̀-ìṣe aṣẹpọ́n (“modifying verb”)
- ọ̀rọ̀-ìṣe aṣẹ̀dá-àpèjúwe (“adjectivizable verb”)
- ọ̀rọ̀-ìṣe aṣẹ̀yán (“modifying verb in grammar”)
- ọ̀rọ̀-ìṣe aṣokùn-ùnfà (“causative verb”)
- ọ̀rọ̀-ìṣe aṣàpọ́nlé (“modifying verb”)
- ọ̀rọ̀-ìṣe aṣàpèjúwe (“descriptive verb”)
- ọ̀rọ̀-ìṣe aṣèròyìn (“report verb”)
- ọ̀rọ̀-ìṣe ayẹ̀rún (“particle-selecting verb”)
- ọ̀rọ̀-ìṣe ẹlẹ́là (“splitting verb”)
- ọ̀rọ̀-ìṣe kíkún (“full verb”)
- ọ̀rọ̀-ìṣe oníbọ̀ (“complex verb”)
- ọ̀rọ̀-ìṣe oníbọ̀ (“complex verb”)
- ọ̀rọ̀-ìṣe ọ̀bọ̀rọ́ (“infinitive verb”)
- ọ̀rọ̀-ìṣe àkànmórúkọ (“compound verb”)
- ọ̀rọ̀-ìṣe àrànmásọdorúkọ (“nominal-assimilating or complex verb”)
- ọ̀rọ̀-ìṣe àsínpọ̀ (“serial verbs”)
- ọ̀rọ̀-ìṣe ìmọ-nǹkan (“cognition verb”)
Related terms
edit- ọ̀rọ̀-anítumọ̀-àdámọ́ (“lexis, content word”)
- ọ̀rọ̀-arọ́pò-orúkọ (“pronoun”)
- ọ̀rọ̀-asopọ̀ (“conjunction”)
- ọ̀rọ̀-atọ́kùn (“preposition”)
- ọ̀rọ̀-orúkọ (“noun”)
- ọ̀rọ̀-ọgbọ́n (“phrase”)
- ọ̀rọ̀-àfetíyá (“ear-loan”)
- ọ̀rọ̀-àkànlò (“idiom”)
- ọ̀rọ̀-àpọ́nlé (“adverb”)
- ọ̀rọ̀-àpèjúwe (“adjective”)
- ọ̀rọ̀-àyálò (“loanword”)
- ọ̀rọ̀-áfojúyá (“eye-loan”)
- ọ̀rọ̀-èdè (“corpus, the words of a language”)
- ọ̀rọ̀-ìró-ìtumọ̀ (“ideophone”)
- ọ̀rọ̀-ìrótumọ̀ (“ideophone”)
References
edit- Awobuluyi, O. (1990) Yoruba Metalanguage (Ede-Iperi Yoruba) Vol. II (A Glossary of English-Yoruba Technical Terms in Language, Literature and Methodology), Ibadan: University Press Ltd.
- Awoyale, Yiwola (2008 December 19) Global Yoruba Lexical Database v. 1.0[3], volume LDC2008L03, Philadelphia: Linguistic Data Consortium, , →ISBN
- Nigerian Educational Research and Development Council (1992) Quadrilingual Glossary of Legislative Terms (English-Hausa-Igbo-Yoruba), Lagos: Federal Cabinet Office and Nigerian Educational Research and Development Council