Àsálà ni èso igi èyíkéyí nínú àwọn ẹ̀yà igi tí àwọn gẹ̀ẹ́sì ń pè ní Juglans . Àsálà jẹ́ ọ̀kan lára èso jíjẹ nígbà tí ó bá ti gbó.[1]

The common walnut in growth
California black walnut in growth.
Inside of a walnut in growth
Walnut shell inside its green husk

Ànfàní èso àsálà

àtúnṣe

Èso àsálà dára fún wíwo àìsàn ìtọ̀ ṣúgà, ó dára fún kí ọpọlọ ó pé.[2]

Ìrísí rẹ̀

àtúnṣe

Èso àsálà rí roboto, èpo rẹ̀ dúdú mìnì, àmọ́ tí a bá fọ tàbí làá, inú rẹ̀ funfun báláú tí ohun kan fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ funfun sì pín èso kan tí a là yí sí ọ̀nà méjì.

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "walnut - meaning of walnut in Longman Dictionary of Contemporary English". LDOCE. Retrieved 2020-03-02. 
  2. "Walnuts". Nuts.com. Retrieved 2020-03-03. 
  NODES
Done 1