Ann Haydon-Jones (abiso Adrianne Shirley Haydon ojoibi 7 October 1938 ni Birmingham, Ileoba Asokan)[1] je ayori table tennis ati tenis tele. O gba apapo She won a total of eight Grand Slam mejo ni asiko re: meta bi enikan, meta bi awon obinrin enimeji, ati meji bi adalu tokunrin tobinrin.[1]

Ann Haydon-Jones
Ann Haydon-Jones after Isner-Mahut match
Orílẹ̀-èdèUnited Kingdom Great Britain
Ọjọ́ìbí7 Oṣù Kẹ̀wá 1938 (1938-10-07) (ọmọ ọdún 86)
Birmingham, England
Ọwọ́ ìgbáyòLeft-handed
Ilé àwọn Akọni1985 (member page)
Ẹnìkan
Iye ife-ẹ̀yẹ113
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 2
Grand Slam Singles results
Open AustrálíàSF (1969)
Open FránsìW (1961, 1966)
WimbledonW (1969)
Open Amẹ́ríkàF (1961, 1967)


  1. 1.0 1.1 "International Tennis Hall of Fame". © 2006 International Tennis Hall of Fame. Retrieved 13 August 2012. .
  NODES
INTERN 2