Bruce Beutler
Bruce Alan Beutler (ojoibi December 29, 1957) je aseoroajesara ati aseiseabinimo ara Amerika.[1] Lapapo pelu Jules A. Hoffmann, won gba abo kan Ebun Nobel 2011 fun Iwosan, fun "iwari won nipa imusise ajesara inu ara" (abo keji lo si Ralph M. Steinman fun "iwari re lori ahamo dendritiki ati ipa re ninu ajesara alamuye").[2]
Bruce Beutler | |
---|---|
Ìbí | 29 Oṣù Kejìlá 1957 Chicago, Illinois |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | American |
Pápá | Immunology |
Ilé-ẹ̀kọ́ | University of Texas Southwestern Medical Center |
Ibi ẹ̀kọ́ | University of Chicago |
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí | 2011 Nobel Prize in Physiology or Medicine |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ http://www.jinfo.org/Nobels_Medicine.html.
- ↑ "Nobel Prize in Physiology or Medicine 2011" (Press release). Nobel Foundation. 3 October 2011.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |