Charlize Theron

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

Charlize Theron (General American English pronunciation: play /ʃɑrˈls ˈθɛrən/; Afrikaans pronunciation: Àdàkọ:IPA-af;[1] ojoibi 7 August 1975) je osere ati ologe aso ara Guusu Afrika[2] to gba Ebun Akademi bi Obinrin Osere Todarajulo.

Charlize Theron
Theron at WonderCon in March 2012 promoting Prometheus.
Ọjọ́ìbí7 Oṣù Kẹjọ 1975 (1975-08-07) (ọmọ ọdún 49)
Benoni, Transvaal Province, South Africa
Orílẹ̀-èdèSouth African and American from 2007
Iṣẹ́Actress, producer, director, fashion model
Ìgbà iṣẹ́1995–present
Alábàálòpọ̀Stuart Townsend (2001–2010)
Àwọn ọmọJackson Theron (adopted)
Websitecharlizetheron.com

Ìbéèrè pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n bíi Theron sì ìlú Benoni ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà, òun nìkan sì ni àwọn òbí rẹ bí.[3][4] Ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kẹfà, ọdún 1991, bàbà Theron tí ó jé ọ̀mùtí gbèrò láti pa Charlize àti ìyá rẹ,[5] o yín ìbon fún wọn, ṣùgbọ́n kò bá wọn, ìyá Charlize bá gbé ìbon tirè ó sì fi pá ọkọ rẹ̀.[6] Ilé ẹjọ́ dá láre, nítorí pé ó fẹ́ pèsè abo fún ohun àti ọmọ rẹ̀.[7][8] Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ tí Putfontein Primary school[9][10][11][12] àti National School of Art ni ìlú Johannesburg.[13][14]

Iṣẹ́

àtúnṣe

Ó bere iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi oníjó, nígbà tí ó wa ni ọmọ ọdún mẹ́rìndínlógún, ó gbà iṣẹ́ mọ́dẹ́lì ni ìdíje tí wọ́n ṣe ní Salerno,[15] èyí sì jẹ kó lọ sí ìlú Milan ni orílẹ̀ èdè Italy.[16] Lẹ́yìn tí ó parí iṣẹ́ mọ́dẹ́lì náà, ó lọ sí ilé New York City, níbẹ̀ sì ni ó ti kọ́ bí wọn ṣe jó, àmọ́ ó padà sèse ni orúkún rẹ̀, èyí sì fà á tí kò fi lè jọ mọ́.


  1. "Charlize Theron Speaks Afrikaans". YouTube. 30 June 2011. Retrieved 21 March 2012. 
  2. Farber, Tanya. "Charlize defends her 'unique' American accent". IOL News. http://www.iol.co.za/news/south-africa/charlize-defends-her-unique-american-accent-1.208000. "I am a South African." 
  3. "Charlize Theron Biography". Hello Magazine. Archived from the original on 25 June 2012. Retrieved 9 August 2012.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. "Benoni, East Rand". www.sa-venues.com. Archived from the original on 17 June 2012. Retrieved 9 August 2012.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. Tron, Gina (26 July 2017). "Charlize Theron Opens Up About Witnessing Mom Shoot And Kill Her Dad". Oxygen. Retrieved 20 April 2019. 
  6. Tron, Gina (26 July 2017). "Charlize Theron Opens Up About Witnessing Mom Shoot And Kill Her Dad". Oxygen. Retrieved 20 April 2019. 
  7. "Charlize Theron". BiographyChannel.co.uk. Archived from the original on 8 December 2009. Retrieved 30 November 2011.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  8. "Charlize Theron's Family Tragedy - ABC News". Abcnews.go.com. 6 January 2006. Retrieved 1 August 2015. 
  9. Àdàkọ:Cite AV media
  10. Chi, Paul (27 November 2011). "Charlize Theron: I Was Teased By Mean Girls in High School". People. Archived from the original on 29 November 2011. Retrieved 30 November 2011.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  11. Àdàkọ:Cite AV media
  12. Àdàkọ:Cite AV media
  13. "Charlize Theron". AccessHollywood.com. Archived from the original on 25 July 2010. Retrieved 4 April 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  14. "Charlize Theron". People. Archived from the original on 1 June 2009. Retrieved 24 October 2009.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  15. "Charlize Theron at Salerno "I could fall in love with Allen" (in Èdè Ítálì). Archived from the original on 5 September 2015. Retrieved 8 August 2012.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  16. Higgins, Charlotte (24 August 2006). "Play It Tough". The Guardian (UK). Archived from the original on 4 May 2009. https://web.archive.org/web/20090504152822/http://www.guardian.co.uk/film/2006/aug/24/cuba. Retrieved 23 February 2008. 
  NODES