Francesca Schiavone (Àdàkọ:IPA-it; ojoibi 23 June 1980 ni Milan) jẹ́ agbá tẹnís ara Itálíà tó di alágbáṣe ní 1998. Ó gba ife-ẹ̀yẹ àwọn ẹnìkan Open Fránsì 2010, láti di obìnrin àkọ́kọ́ ará Itálíà to gba ife-ẹ̀yẹ Grand Slam fún àwọn ẹnìkan. Òhun ló tún gba ipò kejì ní Open Fránsì 2011.

Francesca Schiavone
Orílẹ̀-èdè Italy
IbùgbéMilan, Italy
Ọjọ́ìbí23 Oṣù Kẹfà 1980 (1980-06-23) (ọmọ ọdún 44)
Milan, Italy
Ìga1.66 m (5 ft 5 in)
Ìgbà tódi oníwọ̀fà1998
Ọwọ́ ìgbáyòRight-handed (one-handed backhand)
Ẹ̀bùn owó$9,356,798
Ẹnìkan
Iye ìdíje506–353
Iye ife-ẹ̀yẹ5 WTA
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 4 (31 January 2011)
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́No. 33 (8 October 2012)
Grand Slam Singles results
Open AustrálíàQF (2011)
Open FránsìW (2010); F (2011)
WimbledonQF (2009)
Open Amẹ́ríkàQF (2003, 2010)
Àwọn ìdíje míràn
Ìdíje WTARR (2010)
Ẹniméjì
Iye ìdíje202–169
Iye ife-ẹ̀yẹ7 WTA, 1 ITF
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 8 (12 February 2007)
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́No. 52 (8 October 2012)
Grand Slam Doubles results
Open AustrálíàSF (2009)
Open FránsìF (2008)
WimbledonSF (2012)
Open Amẹ́ríkàSF (2006)
Last updated on: 8 October 2012.


  NODES
languages 1
os 1