Gúnugún
Igúnugún tàbí Igún ni orúkọ irúfẹ́ àwọn ẹyẹ ajẹko ti won jẹ́ irú kan náà ṣùgbọ́n tí wọ́n yàtọ̀ síra wọn, àwọn igún àyé òde-óní ni àwọn èyí tí ó wọ́pọ̀ jùlọ nílùú Kalifọ́níà àti Andean Condors, tí àwọn ti ayé àtijò ma ń jẹ òkú, yálà tènìyàn tàbí ẹranko tó ti kú tí ó sì ti ń rà.
Igúnugún | |
---|---|
Griffon vulture or Eurasian Griffon, Gyps fulvus an Old World Vulture | |
Ìṣètò onísáyẹ́nsì | |
Ìjọba: | |
Ará: | |
Ẹgbẹ́: | |
Families | |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |