George Lucas

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

George Walton Lucas Jr.[2] (bọjọ́ìbí May 14, 1944) ni aṣefílmù, ọlọ́rẹ, àoti oníṣòwò ará Amẹ́ríkà. Lucas gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bíi ẹni tó ṣe àwọn fílmù bíi Star Wars àti Indiana Jones, àti olùdásílẹ̀ àwọn ilẹ́-iṣẹ́ Lucasfilm, LucasArts 'àti Industrial Light & Magic. Òhun ni alága Lucasfilm tẹ́lẹ̀ kí ó tó tàá fún The Walt Disney Company ní 2012.[3]

George Lucas
Ọjọ́ìbíGeorge Walton Lucas Jr.
14 Oṣù Kàrún 1944 (1944-05-14) (ọmọ ọdún 80)
Modesto, California, U.S.
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Southern California
Iṣẹ́
Ìgbà iṣẹ́1965–present
Net worthUS$5 billion (May 2020)[1]
Olólùfẹ́
Marcia Griffin
(m. 1969; div. 1983)

Mellody Hobson
(m. 2013)
Àwọn ọmọ4, including Amanda Lucas, Katie Lucas


  NODES
Done 1