Hiram Rhodes Revels

Olóṣèlú

Hiram Rhodes Revels (September 27, 1827[1] – January 16, 1901) je omo Afrika Amerika akoko mi Ile Alagba U.S. Nitoripe o siwaju gbogbo awon omo Afrika Amerika ni Ile Asoju, ohun ni omo Afrika Amerika akoko ni Kongresi U.S bakanna. O soju fun Mississippi ni 1870 ati 1871 nigba Itunko. Titi to fi di 2011, Revels je ikan ninu awon omo Afrika Amerika mefa pere ti won ti diboyan si Ile Alagba Amerika.

Hiram Rhodes Revels
United States Senator
from Mississippi
In office
February 23, 1870 – March 3, 1871
AsíwájúAlbert G. Brown
Arọ́pòJames L. Alcorn
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1827-09-27)Oṣù Kẹ̀sán 27, 1827 [1]
Fayetteville, North Carolina, U.S.
AláìsíJanuary 16, 1901(1901-01-16) (ọmọ ọdún 73)
Aberdeen, Mississippi, U.S.
Ẹgbẹ́ olóṣèlúRepublican (before 1874), Democratic (1874 on) [2]
(Àwọn) olólùfẹ́Phoebe A. Bass Revels
Alma materKnox College
ProfessionPolitician, Barber, Minister, College President
Military service
Branch/serviceUnion Army
Years of service1863 - 1865
UnitChaplain Corps
Battles/warsAmerican Civil War


  1. 1.0 1.1 Different sources list his birth year as either 1827 or 1822.
  2. Darlene Clark Hine, William C. Hine and Stanley Harrold "The African American Odyssey."
  NODES