Ilé òmìnira ó jẹ́ ilé alájà mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n, èyí tí ó fi ìkàlẹ̀ sí ìwò-oòrùn Tafawa Balewa Square, Onikan ní ìlú Èkó.[1]

Independence House
Building
Alternate namesDefense house
TypeGovernment office
LocationTafawa Balewa Square, Lagos
Coordinates6°26′48.9″N 3°23′56″E / 6.446917°N 3.39889°E / 6.446917; 3.39889Coordinates: 6°26′48.9″N 3°23′56″E / 6.446917°N 3.39889°E / 6.446917; 3.39889
Construction
Completed1961
Floor count25
Main contractorG. Cappa

Àwọn ìjọba orílẹ̀-èdè Bírítéènì (the British government) ni wọ́n fi ètò ilé yìí lélẹ̀ láti jẹ́rìí sí inú rere àti ìfọwọ́sowọ́pọ̀ tí wọ́n ní sí ètò òmìnira orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ní ọdún 1960. [2]

Àwọn kankëré tí wọ́n dúró re ni wọ́n fi kọ́ ilé yìí, ilé yìí jẹ́ èyí tí ó kó onírúurú ilé iṣẹ́ sínú, tí ó sì tún jẹ́ olú ilé iṣẹ́ aláábò lábẹ́ ìṣèjọba Ààrẹ ológun Babangida wọn a sì máa tọ́ka sí ilé yìí gẹ́gẹ́ bíi ilé Aláàbò. Ní ọdún 1993, apá kan lára ilé yìí jóná, láti ìgbà náà ni wọ́n kò ti kọ ibi ara sí i mọ́n. [2]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe


Àdàkọ:Nigeria-struct-stub

Awon itokasi

àtúnṣe
  NODES