James Clerk Maxwell (13 osù ke̩fà, o̩dún 1831 – 5 osù kankànlá, o̩dún 1879) je onimo fisiyiki oniriro ati mathematiiki ara Skotlandi[1]. Aseyori re to se pataki ju ni iro oninagberigberin, to sakojopo gbogbo awon akiyesi, adanwo ati awon isodogba fun itanna, isegberigberin ati optiyiki teletele ti won ko baratan si iru tobaramu.[2] Awon akojopo isodogba re—awon isodogba Maxwell—fihan pe itanna, isegberingberin ati imole na je ifarahanjade isele kanna: papa oninagberingberin. Lati igba yi siwaju, gbogbo awon ofin ati isodogba awon eka wonyi di iru mimuyanju awon isodogba Maxwell. Ise Maxwell ninu isoninagberingberin ti je pipe ni "isodokan tolokiki keji ninu fisiyiki",[3] leyin ekinni ti Isaac Newton se.

James Clerk Maxwell
James Clerk Maxwell (1831–1879)
Ìbí(1831-06-13)13 Oṣù Kẹfà 1831
Edinburgh, Scotland
Aláìsí5 November 1879(1879-11-05) (ọmọ ọdún 48)
Cambridge, England
Ará ìlẹ̀United Kingdom
Ọmọ orílẹ̀-èdèScottish[1]
PápáPhysics and mathematics
Ilé-ẹ̀kọ́Marischal College, Aberdeen, UK
King's College London, UK
University of Cambridge, UK
Ibi ẹ̀kọ́University of Edinburgh, UK
University of Cambridge, UK
Academic advisorsWilliam Hopkins
Notable studentsGeorge Chrystal
Ó gbajúmọ̀ fúnMaxwell's equations
Maxwell distribution
Maxwell's demon
Maxwell's discs
Maxwell speed distribution
Maxwell's theorem
Maxwell material
Generalized Maxwell model
Displacement current
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síSmith's Prize (1854)
Adams Prize (1857)
Rumford Medal (1860)
Religious stanceEvangelical anti-positivist
Signature

Maxwell fihan pe papa onina ati gberingberin n gba inu aaye koja gege bi oniriru, ati pelu isare imole ti ko yi pada. Nipari, ni odun 1864 Maxwell ko iwe "A dynamical theory of the electromagnetic field", ninu ibi ti o ti koko damoran pe ni ooto imole je irusilesoke ninu ohun kanna to n fa isele onina ati gberingberin.[4]

Maxwell tun seda ipinka Maxwell, ona statistiki lati sapejuwe awon ese iro imurin awon efuufu. Awon iwari mejeji yi lo mu igba fisiyiki odeoni waye, o se ifilele ise ojo iwaju ninu papa bi ijebaratan pataki ati isise ero atasere.

Maxwell na lo tun da foto alawo akoko ni 1861, o si tun se ipilese idimule opo ati isopo won bi won se je mimulo ninu awon afara.

Opolopo awon onimo fisiyiki gba Maxwell pe o je onimo sayensi igba orundun 19 to ni ipa pataki julo lori fisiyiki igba orundun 20. Awon afikun re si sayensi je iru kanna bi ti awon Isaac Newton ati Albert Einstein.[5] Ninu iwadi igboro fun egberun odun, iwadi lowo awon onimo fisiyiki pataki julo dibo fun Maxwell gege bi onimo fisiyiki eketa tolokiki julo ni gbogbo igba, leyin Newton ati Einstein nikan.[6] Ni asiko ojoibi odun ogorun Maxwell, Einstein fun ra re juwe ise Maxwell gege bi "eyi to se gbangba julo ati to wulo julo ti fisiyiki ni iriri lati igba Newton."[7] Einstein fi foto Maxwell si ara ogiri yara ikawe re, pelu foto Michael Faraday ati Newton.[8]

Igbesiaye

àtúnṣe

Igba ewe, 1831–39

àtúnṣe

James Clerk Maxwell je bibi ni 13 osù ke̩fà, o̩dún 1831 ni 14 Òpópónà India, Edinburgh, fun John Clerk Maxwell, agbejoro, ati Frances Maxwell (omo Cay).[9]



  1. 1.0 1.1 ""Scottish mathematician and physicist"". Encyclopædia Britannica. Retrieved 24 February 2010. 
  2. "Electromagnetism, Maxwell’s Equations, and Microwaves". IEEE Virtual Museum. 2008. Retrieved 2008-06-02. 
  3. Nahin, P.J., Spectrum, IEEE, Volume 29, Issue 3, March 1992 Page(s):45–
  4. Maxwell, James Clerk (1865). "A dynamical theory of the electromagnetic field" (pdf). Philosophical Transactions of the Royal Society of London 155: 459–512. http://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/1/19/A_Dynamical_Theory_of_the_Electromagnetic_Field.pdf.  (This article accompanied a December 8, 1864 presentation by Maxwell to the Royal Society.)
  5. Tolstoy, p.12
  6. http://news.bbc.co.uk/1/hi/sci/tech/541840.stm
  7. McFall, Patrick "Brainy young James wasn't so daft after all" The Sunday Post, 23 April 2006
  8. "Einstein's Heroes: Imagining the World through the Language of Mathematics", by Robyn Arianrhod UQP, reviewed by Jane Gleeson-White, 10 November 2003, The Sydney Morning Herald.
  9. Oxford Dictionary of National Biography, p506

Iwe fun kika

àtúnṣe
  • Campbell, Lewis; Garnett, William (1882) (PDF). The Life of James Clerk Maxwell. Edinburgh: MacMillan. OCLC 2472869. http://www.sonnetusa.com/bio/maxbio.pdf. Retrieved 2008-02-20. 
  • Glazebrook, R. T. (1896). James Clerk Maxwell and Modern Physics. MacMillan. ISBN 978-1-40672-200-0. 
  • Harman, Peter. M. (2004). Oxford Dictionary of National Biography, volume 37. Oxford University Press. ISBN 019861411X. 
  • Harman, Peter M. (1998). The Natural Philosophy of James Clerk Maxwell. Cambridge University Press. ISBN 052100585X. 
  • Mahon, Basil (2003). The Man Who Changed Everything – the Life of James Clerk Maxwell. Hoboken, NJ: Wiley. ISBN 0470861711. 
  • Porter, Roy (2000). Hutchinson Dictionary of Scientific Biography. Hodder Arnold H&S. ISBN 978-1859863046. 
  • Timoshenko, Stephen (1983). History of Strength of Materials. Courier Dover Publications. ISBN 0486611876. 
  • Tolstoy, Ivan (1982). James Clerk Maxwell: A Biography. University of Chicago Press. ISBN 0-226-80787-8. 

Awon ijapo Interneti

àtúnṣe
 
Wikiquote logo
Nínú Wikiquote a ó rí ọ̀rọ̀ tójẹmọ́:

Àdàkọ:Wikisource author

  NODES
INTERN 3