Ohun tí òǹkọ̀wé ṣiṣẹ́ lé lórí nínú ìwé yìí ìpín èdè Aáfíríkà sí ẹbí. Orí méje ni ìwé náà ní. Orí kìíní ni ó sọ̀rọ̀ nípa ìlàlà tí a lè tẹ̀lé láti pín èdè kan sí ẹbí. Lẹ́yìn èyí ni òǹkọ̀wé wá bẹ̀rẹ̀ sí ní í ṣe àlàyé àwọn ẹbí tí ó pín èdè Aáfíríkà sí. Orí keyì sọ̀rọ̀ nípa Niger-Cong; ẹ̀kẹ́ta, Afrocasiatic; ẹ̀kẹ́rin; Khoisan; ẹ̀kárùn-ún, Chari-Nile; ẹ̀kẹ́fà; Nilo-Saharan nígbà tí orí kéje sọ̀rọ̀ nípa Niger-Kordofania. Yàtọ̀ sí orí méje yìí, ìwé náà ní index to language classification, key to language classification àti index of languages. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ máàpù ni òǹkọ̀wé yà sínú ìwé yìí. Ní ìparí, òǹkọ̀wé ṣe àfikún díẹ̀ sí ìwé yìí ó sì ṣe àtúnṣe àwọn àṣìṣe tí ó ṣe àkíyèsí nínú ìwé náà. Bí àwọn ohun tí ó wa nínú ìwé náà ṣe lọ ní olóríjorí nì yí:

Joseph Greenberg
ÌbíMay 28, 1915 (1915-05-28)
Brooklyn, New York
AláìsíMay 7, 2001 (2001-05-08)
Stanford, California
Ọmọ orílẹ̀-èdèAmerican
Pápálinguistics, African anthropology
Ilé-ẹ̀kọ́Columbia University
Stanford University
Ó gbajúmọ̀ fúnwork in linguistic typology, genetic classification of languages
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síHaile Selassie I Prize for African Research (1967), Talcott Parsons Prize for Social Science (1997)

Iwe ti a yewo

àtúnṣe
  • Joseph H. Greenberg (1966), The Languages of Arica. Bloomingtion; Indian University Press.


  NODES
languages 4
os 5