Kamala Harris
Kamala Devi Harris ( /ˈkɑːmələ/ KAH-mə-lə;[1][2] ọjọ́ìbí October 20, 1964)[3] ni olóṣèlú àti agbẹjọ́rò ará Amẹ́ríkà tó wà ní ipò gẹ́gẹ́bí alàgbà ilẹ́ aṣòfin Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà láti Kalifọ́níà láti ọdún 2017. Òhun ni wọ́n pè lórúkọ fún ipò ìgbákejì ààrẹ sí Joe Biden fún Ẹgbẹ́ Dẹmọkrátíkì nínú ìdìbòyan ààrẹ ọdún 2020 ní Amẹ́ríkà.
Kamala Harris | |
---|---|
Harris in 2017 | |
United States Senator from California | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga January 3, 2017 Serving with Dianne Feinstein | |
Asíwájú | Barbara Boxer |
32nd Attorney General of California | |
In office January 3, 2011 – January 3, 2017 | |
Gómìnà | Jerry Brown |
Asíwájú | Jerry Brown |
Arọ́pò | Xavier Becerra |
27th District Attorney of San Francisco | |
In office January 8, 2004 – January 3, 2011 | |
Asíwájú | Terence Hallinan |
Arọ́pò | George Gascón |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Kamala Devi Harris 20 Oṣù Kẹ̀wá 1964 Oakland, California, United States |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Democratic |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Douglas Emhoff (m. 2014) |
Àwọn ọmọ | 2 stepchildren |
Àwọn òbí | Donald J. Harris Shyamala Gopalan |
Relatives | Maya Harris (sister) Meena Harris (niece) P.V. Gopalan (grandfather) |
Education | Howard University (BA) University of California, Hastings (JD) |
Signature | |
Website | Campaign website |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Thomas, Ken (February 15, 2013). "You Say 'Ka-MILLA;' I Say 'KUH-ma-la.' Both Are Wrong". The Wall Street Journal: 1. "'It's "COMMA-la",' Ms. Harris said with a laugh. 'Just think of "calm". At least I try to be most of the time.'"
- ↑ "Tucker Carlson doesn't pronounce Kamala Harris's name correctly, and doesn't seem to care". National Post. Aug 12, 2020. https://nationalpost.com/news/world/tucker-carlson-doesnt-pronounce-kamala-harriss-name-correctly-and-doesnt-seem-to-care. Retrieved Aug 12, 2020. "The correct pronunciation, however, is 'Comma-la,' with the first syllable instead being emphasized, and the first part of her name sounding like the word 'comma.'"
- ↑ Kamala Harris at the Biographical Directory of the United States Congress
Wikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Kamala Harris |