Konrad Adenauer
Olóṣèlú Ọmọ Orílẹ̀-èdè Germany.
Wọ́n bí Konrad Adenauer ní 1876. Ó kú ní 1967. Òun ni Chancellor West German Federal Republic ní 1949 sí 1963. Òun ni ó dá Christain Democratic Party sílẹ̀ òun sì ni alága rẹ̀ láti 1945 títí di 1966. Lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n ti ṣẹ́gun Jẹ́mánì tán, ó fún Jẹ́mánì ní òfin (Constitution) tí ó fi ni lọ́kàn balẹ́ Ó sì jẹ́ kí àwọn ìlú Òyìnbó yòókù fún Jẹ́mánì láyè nínú ẹgbẹ́ àfọwọ́sowọ́pọ̀ (Western Alliance) wọn. Ó sa gbogbo agbára láti jẹ́ kí ìparí ìjà wà láàrin ilẹ̀ Fransi àti Jẹ́mánì ṣùgbọ́n kò fi àyè (accommodation) gba Rọ́síà.
Konrad Adenauer | |
---|---|
Chancellor of Germany | |
In office 15 September 1949 – 16 October 1963 | |
Ààrẹ | Theodor Heuss (1949-1959) Heinrich Lübke (1959-1969) |
Deputy | Franz Blücher (1949-1957) Ludwig Erhard (1957-1963) |
Asíwájú | Position established Allied military occupation, 1945-1949 Count Lutz Schwerin von Krosigk (1945) |
Arọ́pò | Ludwig Erhard |
Foreign Minister of Germany | |
In office 15 March 1951 – 6 June 1955 | |
Chancellor | Himself |
Asíwájú | Count Lutz Schwerin von Krosigk (1945) |
Arọ́pò | Heinrich von Brentano |
Mayor of Cologne | |
In office 1917–1933 | |
Asíwájú | Ludwig Theodor Ferdinand Max Wallraf |
Arọ́pò | Günter Riesen |
In office 1945–1945 | |
Asíwájú | Robert Brandes |
Arọ́pò | Willi Suth |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Cologne | 5 Oṣù Kínní 1876
Aláìsí | 19 April 1967 Bad Honnef | (ọmọ ọdún 91)
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Centre Party (1906-1945) CDU (1945-1967) |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Emma Weyer Auguste (Gussie) Zinsser |
Alma mater | Yunifásítì ìlú Freiburg Yunifásítì ìlú Munich Yunifásítì ìlú Bonn |
Occupation | Lawyer, Politician |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |