Laurent-Désiré Kabila

Aare Kẹta ti Democratic Republic of Congo

Laurent-Désiré Kabila (27 Osu Kokanla 1939 – 18 Osu Kinni 2001) je Aare ti Orile-ede Olominira Toseluarailu ile Kongo lati ojo 17 Osu Karun 1997, nigba to gbajoba lowo Mobutu Sese Seko, titi di igba ifikupawo re latowo awon oluso re ni ojo 18 Osu Kinni 2001. O je riropo latowo omokunrin re Joseph.

Laurent-Désiré Kabila
Aare OOT ile Kongo
In office
May 17, 1997 – January 18, 2001
AsíwájúMobutu Sese Seko (as President of Zaire)
Arọ́pòJoseph Kabila Kabange
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1939-11-27)27 Oṣù Kọkànlá 1939
Baudouinville, Kongo Beljiom
Aláìsí18 January 2001(2001-01-18) (ọmọ ọdún 61)
Kinshasa, OOT Kongo
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAFDL
(Àwọn) olólùfẹ́Sifa Mahanya
ProfessionRebel leader


  NODES