Melanie Reizes Klein (30 March 1882 – 22 September 1960) je aseituwotoyeokan omo Austria ara Britani to se ida awon ona itoju tuntun fun awon omode to nipa gidi lori orotoyeokan ati ituwotoyeokan igba oni. O je asiwaju ninu isearoye aroye ibaratan ohun.

Melanie Klein (1952)

Igbesiaye

àtúnṣe

O je bibi ni Vienna latowo awon obi elesin Ju,[1] Klein koko wa ituwotoyeokan fun ara re latowo Sándor Ferenczi nigba to ungbe ni Budapest nigba Ogun Agbaye Akoko.

Awon iwe Melanie Klein je kikojo si iwe-akojo merin:

  • Ikowejo 1 - "Ìfẹ́, Ẹ̀bi àti Ìràpadà: Àti Àwọn Iṣé Míràn 1921-1945", London: Hogarth Press.
  • Ikowejo 2 - "The Psychoanalysis of Children", London: Hogarth Press.
  • Ikowejo 3 - "Envy and Gratitude", London: Hogarth Press.
  • Ikowejo 4 - "Narrative of a Child Analysis", London: Hogarth Press.




  NODES
languages 1