Nọ́mbà aláìníìpín
Ninu imo mathematiki Nọ́mbà aláìníìpín je nomba gidi ti ko je nomba oniipin, eyun nomba ti ko se e pin dogba laiseku ikankan, nomba ti ko se ko sile bi m/n ti m ati n ba je odidi, ti n ko gbodo je odo.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |