Naetochukwu Chikwe, tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Naeto C, jẹ́ rápà ti orílẹ̀-èdẹ Nàìjíríà, olórin Afrobeat àti aṣagbátẹ́rù rẹ́kọ́ọ̀dù.

Naeto C
Naeto C
Background information
Orúkọ àbísọNaetochukwu Chikwe
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíiThe 'P', Super C
Ìbẹ̀rẹ̀ Ìpínlẹ̀ ímo, Nàìjíríà
Irú orinRap, Hip-hop
Occupation(s)Olórin, akọrin sílẹ̀ àti Rápà.
Years active2006–present
Labels
  • Storm 360
  • Cerious Music
Associated acts

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀

àtúnṣe

Ìlú Houston, ní Texas ni wọ́n bí i sí, àmọ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Naijiria ni.[1] Gómínà Ìpínlẹ̀ Imo, Emeka Ihedioha yan Naeto C láti jẹ́ olùrànlọ́wọ́ rẹ̀ nígbà tí ó wá sí Ipinle Eko.[2]

Awon Itokasi

àtúnṣe
  1. "Archived copy". Archived from the original on September 28, 2013. Retrieved September 22, 2013. 
  2. "Imo: Gov. Ihedioha names Kema Chikwe’s son, Naeto C special assistant". Daily Post. Retrieved June 21, 2019. 
  NODES