Novak Djokovic
Novak Djokovic (Kirilliki Serbia: Новак Ђоковић; Novak Đoković; Àdàkọ:IPA-sh; ibi ní Belgrade ọjọ́ ìbí Oṣù Kàrún 22, 1987) jẹ́ agbá tẹ́nìs alagbase ará Sérbíà, tó di Ipò kínín ATP mú lati Ọjọ́ kẹrin Oṣù keje Ọ́dún 2011 dé Oṣù keje Ọdún 2012. Djokovic ti gba ife ẹ̀yẹ àwọn enìkan Grand Slam mejo, ó gba àwọń ife-eye idíje ATP World Tour Masters 1000 méjìlá, ó sì tún jẹ́ ọmó-ẹgbẹ́ Ife Eye Davis Sérbíà tó borí ní odún 2010. Ọ̀pọ̀̀ àwọn olùtúwò eré-ìdárayá, olùgbéwò tẹnìs, à̀ti àwọn atayò lọ́́wọ́ àti tẹ́lẹ̀ gbà pé Djokovic ni atayò tẹnìs to gbòkìkíjùlo.[2][3][4][5][6]
Orúkọ | Novak Đoković |
---|---|
Orílẹ̀-èdè | Sérbíà |
Ibùgbé | Monte Carlo |
Ọjọ́ìbí | 22 Oṣù Kàrún 1987 Belgrade, Sérbíà |
Ìga | 1.88 m (6 ft 1 in) |
Ìgbà tódi oníwọ̀fà | 2003 |
Ọwọ́ ìgbáyò | Right-handed (two-handed backhand) |
Olùkọ́ni | Dejan Petrovic (2004–2005) Riccardo Piatti (2005–2006) Marián Vajda (2006–) Mark Woodforde (2007) Todd Martin (2009–2010) Boris Becker (2013–) |
Ẹ̀bùn owó | $82,346,218 |
Ojúewé Íntánẹ́ẹ̀tì | novakdjokovic.com |
Ẹnìkan | |
Iye ìdíje | 652–143 (82.01% in Grand Slam and ATP World Tour main draw matches, and in Davis Cup) |
Iye ife-ẹ̀yẹ | 54 (10th in the Open Era) |
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 1 (4 July 2011) |
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́ | No. 1 (13 July 2015)[1] |
Grand Slam Singles results | |
Open Austrálíà | W (2008, 2011, 2012, 2013, 2015) |
Open Fránsì | W (2016) |
Wimbledon | W (2011, 2014, 2015) |
Open Amẹ́ríkà | W (2011) |
Àwọn ìdíje míràn | |
Ìdíje ATP | W (2008, 2012, 2013, 2014) |
Ìdíje Òlímpíkì | Bronze medal (2008) |
Ẹniméjì | |
Iye ìdíje | 37–52 |
Iye ife-ẹ̀yẹ | 1 |
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 114 (30 November 2009) |
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́ | No. 287 (13 July 2015) |
Grand Slam Doubles results | |
Open Austrálíà | 1R (2006, 2007) |
Open Fránsì | 1R (2006) |
Wimbledon | 2R (2006) |
Open Amẹ́ríkà | 1R (2006) |
Àwọn Ìdíje Ẹgbẹ́ Agbáyò | |
Davis Cup | W (2010) |
Hopman Cup | F (2008, 2013) |
Last updated on: 13 July 2015
Signature of Novak Djokovic. |
Iye ẹ̀ṣọ́ Olympiki | |||
Adíje fún Sérbíà | |||
---|---|---|---|
Men's Tennis | |||
Bàbà | 2008 Beijing | Singles |
Àwọn ìtókasí
àtúnṣe- ↑ atpworldtour.com
- ↑ "Novak Djokovic is one of the greatest tennis players ever, says Pat Cash". Archived from the original on 27 June 2013. Retrieved 10 February 2012.
- ↑ "Novak Djokovic v Rafael Nadal: Players & pundits hail 'greatest' match". Retrieved 5 March 2012.
- ↑ "Murray buoyed by Djokovic scalp". Retrieved 15 March 2012.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Rod Laver's 10 best past and present players". Retrieved 7 June 2012.
- ↑ "Tim Henman knows Andy Murray won’t worry over critics". Retrieved 14 August 2012.
Wikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Novak Đoković |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |