Pelé
Olóṣèlú Ọmọ Orílẹ̀-èdè Brazil (1940–2022)
Edison Arantes do Nascimento,[3] KBE (bíi Ọjọ́ kẹtàlélógún Oṣù kẹwá Ọdún 1940, Três Corações, Minas Gerais, Brazil), tí wọ́n mọ̀ sí Pelé (Brazilian Pípè ni Potogí: [peˈlɛ], usual Pípè: /ˈpɛleɪ/) jẹ́ agbábọ́ọ̀́lù-ẹlẹ́sẹ̀ tó ti fẹ̀yìntì ọmọ orílẹ̀-èdè Brasil.[4]
Nípa rẹ̀ | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Edson Arantes do Nascimento | ||
Ọjọ́ ìbí | 23 Oṣù Kẹ̀wá 1940 | ||
Ibùdó ìbí | Três Corações, Brazil | ||
Ìga | 1.73 m (5 ft 8 in) | ||
Ipò | Attacking midfielder/Forward | ||
Èwe | |||
1952–1956 | Bauru AC | ||
Alágbàtà* | |||
Odún | Ẹgbẹ́ | Ìkópa† | (Gol)† |
1956–1974 | Santos | 605 | (589[1]) |
1975–1977 | New York Cosmos | 64 | (37[2]) |
Lápapọ̀ | 669 | (626) | |
Agbábọ́ọ̀lù ọmọorílẹ̀-èdè | |||
1957–1971 | Brazil | 92 | (77) |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Àwọ́n Itọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedSPSRSPS
- ↑ "NASL Player Profile - Pele". Nasljerseys.com. 1940-10-23. Retrieved 2010-06-12.
- ↑ Àdàkọ:Cite video
- ↑ "40 years on: how New York Cosmos lured Pelé to a football wasteland". The Guardian. Retrieved 3 January 2016.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |