Peter Abelard A bí i ní 1079. Ó kú ní 1142. Ó jé òkan lára àwon tí ó sèdá ohun tí a n pè ní scholastic theology. Olùkó ni ní Paris. Òpò akékòó ni ó máa n wá sódò rè. Òpin ìfé láàrin òun àti Heliose kò dára

Pierre Abélard
"Abaelardus and Heloïse surprised by Master Fulbert", by Romanticist painter Jean Vignaud (1819)
OrúkọPierre Abélard
Ìbí1079
Aláìsí21 April 1142
ÌgbàMedieval Philosophy
AgbègbèWestern Philosophers
Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́Scholasticism
Ìjẹlógún ganganMetaphysics, Logic, Philosophy of language, Theology
Àròwá pàtàkìConceptualism, Scholasticism



  NODES