STS-7 je iranlose Oko alobo Ofurufu NASA, eyi ni iranlose ti Oko alobo Ofurufu Challenger lo lati gbe opo satelaiti lo si oju ofurufu. Oko na gbera lati Kennedy Space Center ni 18 June 1983, o si bale si Edwards Air Force Base ni 24 June. STS-7 ni iranlose oko alobo keje ati iranlose keji Challenger. Bakanna o tun je ifoloke ofurufu akoko Amerika to ni obinrin arinlofurufu.

STS-7
Àmìyẹ́sí ìránlọṣe
Statistiki ìránlọṣe
Orúkọ ìránlọṣeSTS-7
Space shuttleChallenger
Launch pad39-A
Launch date18 June 1983, 11:33:00 UTC
Landing24 June 1983, 13:56:59 UTC
Edwards Air Force Base
Mission duration6 days, 2 hours, 23 minutes, 59 seconds
Number of orbits97
Orbital altitude296 kilometres (184 mi) to 315 kilometres (196 mi)
Orbital inclination28.5°
Distance traveled4,072,553 kilometres (2,530,567 mi)
Crew photo
L-R: Ride, Fabian, Crippen, Thagard, Hauck
Ìránlọṣe bíbátan
Ìránlọṣe kíkọjásẹ́yìn Ìránlọṣe kíkànníwájú
STS-6 STS-6 STS-8 STS-8


  NODES
languages 1
os 4