Saint Ann's Bay
Saint Ann's Bay ni ìlú kan ní Jamáíkà, ibẹ̀ ni olùìlú Saint Ann Parish. Iye àwọn ènìyàn ibẹ̀ tó 13,671 ní ọdún 2009.[1]
Saint Ann's Bay | |
---|---|
Town | |
Coordinates: 18°26′10″N 77°12′07″W / 18.436°N 77.202°WCoordinates: 18°26′10″N 77°12′07″W / 18.436°N 77.202°W | |
Orílẹ̀-èdè | Jamáíkà |
County | Middlesex |
Parish | Saint Ann |
Population (2009) | |
• Total | 13,671 |
Time zone | UTC-5 (EST) |
Floyd Lloyd àti Burning Spear tk wọ́n jẹ́ olórin, àti Marcus Garvey wá láti ibẹ̀.
Itokasi
àtúnṣe- ↑ "Jamaica: largest cities and towns and statistics of their population". World Gazetteer. Archived from the original on 5 December 2012. Retrieved 21 December 2009.