Tòmátò
Tòmátò ní irúgbìn tó po ti o si kéré. Ó da fún ara wa. Tí ó bá ti pón ó ma n pupa, bi ósͅe n pón lósì ma ma tóbi. Orísͅìrisì tòmátò ló wà ní àgbáyé. Wón ma n pe tòmátò ni èso nítorí pé ó ní ìrúgbìn tó pòͅ. Sͅùgbóͅn àwoͅn ènìyàn ma n pé tòmátò l’ágbàye ni èfóͅ, wóͅn sì dèͅ má n se bi èfóͅ.
Tòmátò | |
---|---|
Cross-section and full view of a ripe tomato | |
Ìṣètò onísáyẹ́nsì | |
Ìjọba: | |
(unranked): | |
(unranked): | |
Ìtò: | |
Ìdílé: | |
Ìbátan: | |
Irú: | S. lycopersicum
|
Ìfúnlórúkọ méjì | |
Solanum lycopersicum | |
Synonyms | |
Lycopersicon lycopersicum |
Bí Oúnje
àtúnṣeTòmátò je eso kan ti a fi maa n se obe. Ti o ba pon tan, kii pe ra nitori naa, awon oloja maa n fe tete ta a tan. Ile Hausa ni gbigbe tòmátò wopo si ju ni ile Naijiria.
Wikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Solanum lycopersicum |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |