William Butler Yeats
Williams Butler Yeats (pípè /ˈjeɪts/; 13 June 1865–28 January 1939) je akewi ati onimo ninu Litireso ede Geesi. Omo ile Geesi ni. A bí W.B. Yeats ní 1865. Ó kú ní 1939. Ó kọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ewì. O gbà pé nǹkan tí ó bá ṣẹlẹ̀ ní ẹgbẹ̀rún méjì ọdún kan ni yóò tún ṣẹlẹ̀ ní ẹgbẹrún méjì ọdún tí ó bá tún tẹ̀lé é.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |